Born on September 24, 1970, in Lagos State, Nigeria, Shola Allyson-Obaniyi, or Sola Allyson, discovered her musical gift early in life. Rooted in Yoruba culture and nurtured in a Christian household, her foray into gospel music seamlessly blended her rich heritage with deep faith.
Sola Allyson’s voice carries the echoes of sincerity, resonating profoundly with listeners. With a career spanning decades, she symbolizes authenticity in a genre known for its spiritual depth and cultural richness. Her discography, featuring hits like “Iyin,” “Ope,” and the iconic “Eji Owuro,” mirrors her commitment to creating music that transcends boundaries and speaks to the soul.
The title, “Eji Owuro,” translates to “Morning Time” in English, encapsulating the song’s essence—a call to worship and gratitude at the dawn of a new day. In this revamped version, Sola Allyson weaves her signature vocals into a tapestry of rich instrumentation, breathing new life into a melody that has withstood the test of time.
Sola Allyson’s influence extends far beyond the music realm. Her authenticity, both as an artist and an individual, has earned her respect in Nigeria and beyond. Through her dedication to preserving the cultural nuances of Yoruba spirituality, seamlessly infused into her music, she has become a cultural ambassador bridging the gap between tradition and modernity.
DOWNLOAD I SPEAK OF JESUS Mp3 SONG
Sola Allyson – Eji Owuro 2.0 Lyrics
Duro timi o, Ololufe
Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan Femi bi oju ti n f’emu Femi bi irun ti n f’ori Femi bi eyin ti n f’enu Femi teerin teerin Femi taayo taayo Femi taara taara Ololufe feran mi laisetan Femi bi oju ti n f’emu Femi bi irun ti n f’ori Femi bi eyin ti n f’enu Femi teerin teerin Femi taayo taayo Femi taara taara Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan Ba mi s’ootito, Mo fe o tooto Ba mi s’ododo, Mo fe o pelu ododo Ba mi s’ootito, (Ololufe) Mo fe o tooto Ba mi s’ododo, Mo fe o pelu ododo B’ogiri o ba la’nu, Alangba o le w’ogiri B’ogiri o ba la’nu, Alangba o le w’ogiri Eleda lo yan wa papo, Esu ko ni yawa o Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. A ma lowo lowo A ma kole mole A ma bimo lemo A ma sayo mayo A ma shola mola Ka sa mufe Eledumare se, laisetan. A ma lowo lowo A ma kole mole A ma bimo lemo A ma sayo mayo A ma shola mola Ka sa mufe Eledumare se, laisetan. Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. Gb’amoran mi, Ololufemi! Oluranlowo la fi mi se fun o lat’orun wa F’eti s’amoran mi, Ololufemi! Oluranlowo la fi mi se fun o lat’orun wa Kaj’orin ka s’ogo, l’oruko Olorun Alabinrin la fi mi se fun o lat’orun wa M’okan ku ro ni asan aye Etan o da n kankan fun ni Ife at’ope lo le mu wa l’aye ja lai labawon M’okan ku ro ni asan aye Etan o da n kankan fun ni Ife at’ope lo le mu wa l’aye ja lai labawon Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo Duro timi o, Ololufe Ife ti ko leetan rara ni ko ba mi lo…